Kíkọ àti Kíkà onka Yorùbá ni nọ́mbà àti Èdè (100 – 200)
YORÙBÁ
ṢÁÁ KÍNNÍ (FIRST TERM)
ỌṢẸ KÍNNÍ (WEEK 1)
ALÁKỌỌBẸ̀RẸ̀ KẸFÀ (BASIC 6)
ORÍ Ọ̀RỌ̀ (TOPIC): Kíkọ àti Kíkà ònka Yorùbá ni nọ́mbà àti Èdè
ÈRÒǸGBÀ (PERFORMANCE OBJECTIVES)
- Akẹ́kọ̀ọ́ yóò lè::
- ÈDÈ – Ka onka láti ọgọ́rùn dé igba (100 – 200);
- Dá fígọ̀ ònka láti ọgọ́rùn de igba (100 – 200) mọ̀.
- ÀṢÀ – dárúkọ oríṣiríṣi àṣà ìkíni ní Ilé Yorùbá.
- LITIRESO – Kíkà Ìwé tí Ìjọba yàn àti ìdáhùn fún Ìbéèrè.
ENTRY BEHAVIOR
- The pupils are required to already have learnt…
OHUN-ÈLÒ ÌKỌ́NI (INSTRUCTIONAL MATERIALS)
- The teacher will teach the lesson with the aid of:
- Kádibọ́ọ̀dù tí a ònka láti ọgọ́rùn dé igba (100 – 200) sí.
- Káàdì pélépé.
REFERENCE MATERIALS
- Scheme of Work
- 9 – Years Basic Education Curriculum
- All Relevant Materials
- Online Materials
CONTENT OF THE LESSON
ÒNKA LÁTI ỌGỌ́RÙN DÉ IGBA
Number Nọ́mbà Number Nọ́mbà Number Nọ́mbà
1 ení 11 ọ̀kanlá 25 (30−5) ẹ́ẹdọ́gbọ̀n
2 èjì 12 (10+2) èjìlá 30 ọgbọ̀n
3 ẹ̀ta 13 (10+3) ẹ̀talá 35 (20×2−5) aárùndílogójì
4 ẹ̀rin 14 (10+4 ) ẹ̀rinlá 40 (20×2) ogójì
5 àrún 15 (20-5). ẹ́ẹdógún 50 (20×3−10) àádọ́ta
6 ẹ̀fà 16 (20-4) ẹẹ́rìndílógún 60 (20×3) ọgọ́ta
7 éje 17 (20-3) eétàdílógún 70 (20×4-10) àádọ́rin
8 ẹ́jọ 18 (20-2) eéjìdílógún 80 (20×4) ọgọ́rin
9 ẹ́sàn 19 (20-1) oókàndílógún 90 (20×5-10) àádọ́rùn
10 ẹ́wàá 20 ogún 100 (20×5) ọgọ́rùn › ọrún
110 (20×6-10) àádọ́fà
120 (20×6) ọgọ́fà
130 (20×7-10) àádóje
140 (20×2) ogóje
150 (20×8) àádọ́jọ
160 (20×8) ọgọ́jọ
170 (20×9−10) àádọ́sán
180 (20×9) ọgọ́sàn
190 (200-10) ẹ̀wadilúɡba
200 igba
Àṣà Ìkíni ní Ilé Yorùbá – English translation
Ẹ káàrọ̀ akẹ́kọ̀ọ́ wa, Lónìí, a ó tẹsíwájú nínú Àṣà Ìkíni ní èdè Yorùbá. A ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú Ìkíni ojoojúmọ́.
Ẹ káàrọ̀ (someone older than you) Good morning
2. Káàrọ (someone of your age mate or friend) – Good morning
3. Ẹ káàsàn án – Good Afternoon
4. Ẹ kúròlé ẹ́ – Good Evening
5. Ó dàárọ̀ – Good night
6. Báwo ni? – How are you?
7. Mọ wà dáadáa, ẹ ṣé – I’m fine, thank you.
8. Báwo ni iṣẹ́? – How is work?
9. Ẹ ṣé , A dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run – Fine, thank to God
10. Ẹbí ń kó? – How is family?
11. Àwọn òbí rẹ ń kó? – How is your parents?
12. Ẹ kú iṣẹ́ – Weldone
13. Ó dàbọ̀ – Goodbye
LITIRESO
- Kíkà Ìwé tí ÌÌjọba yàn àti Ìdáhùn fún Ìbéèrè.
PRESENTATION
- To deliver the lesson, the teacher adopts the following steps:
- To introduce the lesson, the teacher revises the previous lesson. Based on this, he/she asks the pupils some questions;
- Kọ ònka láti ọgọ́rùn dé igba (100 – 200) sí ojú pátákó.
- Akẹ́kọ̀ọ́ – ka ọgọ́rùn dé igba (100 – 200).
- Tọ akẹ́kọ̀ọ́ sọ́nà láti kà ònka láti ọgọ́rùn dé igba (100 – 200);
- Akẹ́kọ̀ọ́ – Dá ònka tí a kọ sójú pátákó mọ ní ọ̀kọ̀ọ̀kan.
- Ṣe àlàyé ìgbésẹ̀ ònka kọ̀ọ̀kan ní kíkún;
- Akẹ́kọ̀ọ́ – Kọ ònka tí olùkọ́ kọ sí ojú pátákó sínú ìwé.
- Ṣe àlàyé àti ìtumọ̀ àṣà ìkíni ní ilé Yorùbá.
- Akẹ́kọ̀ọ́ – ṣe bí a tí ń kíni ní ilé Yorùbá.
- Olùkọ́ àti akẹ́kọ̀ọ́ – Kíkà Ìwé tí ÌÌjọba yàn àti Ìdáhùn fún Ìbéèrè.
[click]
CONCLUSION
- To conclude the lesson for the week, the teacher revises the entire lesson and links it to the following week’s lesson.
ÌTỌ́NISỌ́NÀ FÚN ÌGBÉLÉWỌ̀N (LESSON EVALUATION)
- Kí a kẹ́kọ̀ọ́:
- ÈDÈ – Ka ònka láti ọgọ́rùn dé igba (100 – 200);
- Kọ ònka tí olùkọ́ kọ fígọ̀ rẹ̀ sí ojú pátákó sínú ìwé.
- ÀṢÀ – dárúkọ oríṣiríṣi àṣà ìkíni ní Ilé Yorùbá.
- LITIRESO – Kíkà Ìwé tí Ìjọba yàn àti ìdáhùn fún Ìbéèrè.