Third Term Examination Yoruba Junior Secondary Schools – JSS 1 (Basic 7) Exam Questions
YORUBA THIRD TERM EXAMINATION JUNIOR SECONDARY SCHOOLS JSS 1 (BASIC 7) EXAM QUESTIONS
SECTION A – OBJECTIVES
INSTRUCTION – DAHUN GBOGBO IBEERE WONYI
1. Kinni oro-oruko ninu gbolohun yii “Tunde ji eja je” _______.
(a) Tunde
(b) Eja
(d) Ji”
2. Kinni oro-ise ninu gbolohun yii “mo ra moto meta” _______.
(a) Moto
(b) Mo
(d) Ra
3. Kinni oro-aropo oruko ninu gbolohun _______.
(a) Lanaa
(b) Mo
(d) Wa
4. Kinni oro aropo- afarajoruko ninu gbolohun yii “ oun lo fa iwe mi ya” _______.
(a) Iwe
(b) Oun
(d) Fa
5. Kinni oro_Atokun ninu gbolohun yii “Mo lo si ilu- Oyo _______.
(a) Si
(b) Lo
(d) Oyo
6. Kinni oro-aponle ninu gbolohun yii “Ata naa pon wee” _______.
(a) Naa
(b) Ata
(d) Wee
7. Kinni oro-asopo ninu gbolohun yii “Jide ti olu je ore” _______.
(a) Olu
(b) Ati
(d) Je
8. Kinni oro-apejuwe ninu gbolohun yii “ Aja dudu ni mo ra” _______.
(a) Dudu
(b) ni
(d) Ra
9. Apeere ere-idaraya ni wonyi _______.
(a) Bojuboju
(b) Ewe
(d) Igi
10. Kinni itumo oro- ayalo yii “Bread” a di _______.
(a) Buga
(b) Bureedi
(d) Buredi
11. Alifabeeti ede yoruba meloo ni o wa _______.
(a) Ogun
(b) Arundinlogbon
(d) Eeewa
12. Iro-Faweli Airanmupe je meloo _______.
(a) Meje
(b) Meta
(d) Eewa
13. Iro-faweli Aranmupe je loo _______.
(a) Marun-un
(b) Meta
(d) Meji
14. Iro-konsonati je meloo _______.
(a) Mejidinlogun
(b) Ogun
(d) Ogbon
15. Iro-ohun je meloo _______.
(a) Merin
(b) Mefa
(d) Meta
16. Akoto ede Yoruba “Eiye A di _______.
(a) Eiye
(b) Eeye
(d) Eye
17. Akoto ede Yoruba “ mushin a di _______.
(a) Musin
(b) Shin
(d) Mu
18. Aroko-Asapejuwe da lori bi a ti se sapejuwe _________ se ri.
(a) Nnkan
(b) Juwe
(d) Mori
19. Kinni onka “40 lede Yoruba _______.
(a) Ogoji
(b) Ogbon
(d) Ogun
20. Ere-idaraya je orin ti awon _______ maa n ko nigba irole.
(a) Agba
(b) Omode
(d) Odo
21. Ninu iwe-kika “iwoye-Akewi dahun ibeere yii “Bi eye _______ ninu igbo.
(a) Adan
(b) Igbin
(d) Aja
22. Akewi ko _______ la san oyeni on wo.
(a) Sukun
(b) Dake
(d) Sun
23. Idi re ti mo fi _______ fun yin.
(a) Gbope
(b) Gbo suba
(d) Ogo
24. Oro _______ oro oloye ni yoo tenu won bo.
(a) Ologbon
(b) Oye
(d) Imo
25. Iwa rere leso _______.
(a) Iwa
(b) Ibaje
(d) Eniyan
26. Enikan ki fola _______ epo laa fola je.
(a) Jiyo
(b) Epo
(d) oro lola
27. A maa mu ki a _______ fomo won lola.
(a) Ope
(b) Ore
(d) Saan
28. _______ araa re loo fi se eyi.
(a) Ori
(b) Owo
(d) Aso
29. Nigba to runmila fi _______ le iwa lo.
(a) Rere
(b) Owo
(d) Iwa
30. Won so forunmila _______ o ri iwa.
(a) Pawon
(b) Leke
(d) Iro
IPIN- KEJI – DAHUN IBEERE META NI IPIN YII? NINU IWE-KIKA YII
QUESTION 1
A. E ma fi wa so iwe nu?
B. Ore tete __________ iwa re to ti baje?
D. Make gba esulaaye ______ ti o ?
E. Ore _______ ti ro arose aforitidie lo nilo?
Ẹ. Akoko ire ati ayo yoo de ?
QUESTION 2
A. Kin-in-ni oro –oruko?
B. Se apeere oro –orúkọ?
QUESTION 3 – Marun-un pere?
A. Kin-in-ni Ere-idaraya?
B. Daruko apeere, ere.Idaraya
QUESTION 4 – Marun-un pere se alaye meta ninu won?
A. Kin-in-ni oro-Ayalo?
B. Ona meloo ni o pin si?
C. Tumo awon oro won yi si ede Yoruba
QUESTION 5 – Ede Geesi Ede Yoruba
A. Biro _______
B. Pencil _______
D. Bread _______
E. Chalk _______
Ẹ. Book _______
F. Pot _______
G. Basket _______
GB. Money _______
H. Bed _______
I. Food _______