Third Term Examination Yoruba Senior Secondary Schools (SS 2) Exam Questions

YORUBA THIRD TERM EXAMINATION SENIOR SECONDARY SCHOOLS (SS 2) EXAM QUESTIONS

SECTION A – OBJECTIVES

INSTRUCTION – CHOOSE THE CORRECT ANSWER FROM THE OPTIONS A – D.

1. Silebu meloo ni o wa ninu oro yii “ Olojunla” _____.

(a) merin

(b) marun

(d) meji

 

2. Aroko- oni soro ngbesi wa laarin eniyan meloo _____.

(a) meji

(b) ikan

(d) pupo

 

3. O maa n dalori “ ile daraju oko lo _____.

(a) eniyan meji

(b) eniyan kan

(d) repete

 

4. Ise- Abinibi ni ise ti a ba lowo awon _____ wá.

(a) Agbe

(b) Oko

(d) Apeja

 

5. Awon Agbe ni won maa n _____ nnkan loko.

(a) gbin

(b) da

(d) ko

 

6. Orisirisii oun ogbin loko ni _____.

(a) isu, ila, ata, efon

(b) igi, ewe

(d) aso, igi

 

7. Awon oun ti a le fi agbado se ni _____.

(a) ogi, guguru eko

(b) ole, epa, igi

(d) Ewe, igi, ila

 

8. Awon oun ti a le fi isuse ni _____.

(a) iyan, dindin, sise

(b) ogi, epa, efon

(d) owo, aso, eni

 

9. Awon oun ti a le fi “ Ege” se ni _____.

(a) Elubo, funfun

(b) igi, ewe

(d) asaro, ole

 

10. Awon oun ti a le fi “ ogede” se ni _____.

(a) dindin, ipekere, sose

(b) jije, riro

(d) rire, sisun

 

11. Kinni oro- oruko oluwa ninu Gbolohun yii “ morire lo si ilu Oyinbo lanaa” _____.

(a) oyinbo

(b) lanaa

(d) morire

 

12. Kinni oro- oruko abo ninu Gbolohun yii “ mo je eba” _____.

(a) eba

(b) je

(d) mo

 

13. Kinni oro- oruko eyan ninu _____“ Awon akeko n pari wo”.

(a) akekoo

(b) pariwo

(d) awon

 

14. Pari owe wonyi “ Apeleyin Egungun eran ni _____ je.

(a) je

(b) eran

(d) yoo

 

15. Kinni onka “ 120” lede Yoruba _____.

(a) Ogofa

(b) Ogoji

(d) Ogun

 

16. Awon wo ni a maa n ko leta-gbefe si _____.

(a) odo

(b) agba

(d) obi

 

17. Adiresi meloo ni leta gbefe maa n ni _____.

(a) meji

(b) ikan

(d) meta

 

18. Awon wo ni a maan ko leta- Aigbefe si _____.

(a) ore

(b) ile- ise

(d) baba

 

19. Adiresi meloo ni leta- Aigbefe ni _____.

(a) merin

(b) meji

(d) ikan

 

20. Apa ibo ni Adiresi akoleta yoo wan i _____.

(a) otun

(b) osi

(d) egbe

 

21. Awon orisa ile Yoruba ni _____.

(a) Sango

(b) Abore

(d) Ifa

22. Orisa wo ni o maa n yo ina lenu ni _____.

(a) Ogun

(b) Oyu

(d) Sango

 

23. Orisa wo ni won maa n bo ni ilu osogbo ni _____.

(a) Osun

(b) Oba

(d) Oya

 

24. Iya meloo ni sango ni _____.

(a) Meji

(b) Meta

(d) Merin

 

25. Orisa wo ni obinrin ko gbo do fi oju ri ni _____.

(a) Egungun

(b) Oro

(d) Eyo

 

26. Ninu iwe-kika “OGun-omode” dahun ibeere wonyi “awon meloo ni won jo n se ere papo ni _____.

(a) Meta

(b) Meji

(d) Merin

 

27. Nibo ni won ti fe lo sere ninu _____.

(a) Oko

(b) Koko

(d) Ile

 

28. Kinni oruko awon meteeta yiii ni _____.

(a) Akanmu, Dolapo, iyiola

(b) Bisi, titi, olajide

(d) Bisi, Tope, Bolaji

 

29. Taa ni eniti o ta roba fun fola lori _____.

(a) Akanmu

(b) Iyiola

(d) Dolapo

 

30. Awon ore meloo ni won n ba ara won ja _____.

(a) Meji

(b) Ikan

(d) Meta

 

ÌPÍN – KEJÌ

DAHUN IBEERE META NINU IPIN YII?

QUESTION 1

A. Daruko orisa ile Yoruba marun-un ti o mo?

B. Se apeere Agbara ti enikan kan ni?

 

QUESTION 2

A. Kin-in-ni silebu ede Yoruba?

B. Pin awon oro won yi si iye silebu to je?

I. Arogodoganyin?

II. Oloju kokoro-nla?

III. Agbadarigi

IV. Baba

V. Oronbo

VI. Benbe

VII. Oluwa

VIII. Konsonanti

IX. Ekunrere

 

QUESTION 4

A Kin-in-ni ihun – oro siseda oro orúkọ?

B. ona meloo ni o pin si?

D. Se apeere “lilo afomo ibere ati apetunpe marun, marun-un?

 

QUESTION 5

Ko aroko ajemo isipaya lori oun ti ale fi “omi” se alaye ekun rere lori re?

 

QUESTION 5

Ninu iwe kika ninu “Ogun omode” dahun ibeere wonyii

A. Awon wo ni won beru fun egba jije?

B. kinni oruko egbon delodun obinrin?

D. kinni oruko aburo Ayoka?

e. Ile awon taa ni won tin je amala dudu?

ẹ. Kinni oruko onkowe iwe kika naa?