Third Term Yoruba Examination Junior Secondary Schools – JSS 3 (Basic 9) Mock Exam Questions
YORUBA THIRD TERM EXAMINATION JUNIOR SECONDARY SCHOOL – JSS 3 EXAM QUESTIONS
DURATION – 2½
SECTION A – OBJECTIVES
INSTRUCTION – DAHUN GBOGBO IBEERE WONYI. ALL QUESTIONS CARRY EQUAL MARK
1. Kinni itan isedale agba alaye kiki da _____ ni abe orun wa tele
(a) Omi
(b) Okun
(d) Osa
2. _____ ran oduduwa lati orun wa da aye
(a) Olorun
(b) Eledumare
(d) Olorun
3. Oduduwa fi _____ ro lati orun.
(a) seeni
(b) okun
(d) ewonro
4. Ile to n fe yin ni odi _____.
(a) Ile-Ife
(b) Oyo
(d) Ibadan
5. Oro enu _____ ni olorun fid a ayé.
(a) Ase
(b) Oro
(d) Opa
6. Igbagbo yii han ninu bibeli _____.
(a) Pita
(b) Genesisi
(d) Mose
7. Ojo mefa ni olorun fi da aye o si simi ni ojo _____.
(a) Kejo
(b) Kefa
(d) Keje
8. O hun-nla kan roboto bii _____ ti o gbona janjan.
(a) Boolu
(b) Eegi
(d) Igba
9. Awon ibi ti ko fon de ni odi odo omi _____ ati _____.
(a) Ope ati igi
(b) Okun ati osa
(d) Ile ati odo
10. Akufo re ti afefe fe silo di ile _____.
(a) Gbigbona
(b) Gbigbe
(d) Tutu
11. Kinni Eyan – Asonka ninu gbolohun yii “ile mefa ni moko”.
(a) ile
(b) ko
(d) mefa
12. Kinni Eyan Asapejuwe ninu gbolohun yii “omo pu pa ni titi”.
(a) Pupa
(b) Titi
(d) Omo
13. Kinni Eyan aropo oruko ninu gbolohun yii “o so iwe mi nu”.
(a) o
(b) iwe
(d) So
14. Osu _____ ni awon obirin fi maa n run oyun.
(a) Meje
(b) Mejo
(d) mesan
15. Ojo _____ ni won n somoloruko nile Yoruba.
(a) kefa
(b) kejo
(d) keje
16. Awon oun isomoloruko niyi.
(a) Adun obi
(b) omi Ata
(d) epo ororo
17. ________ ni babanla awon Yoruba.
(a) Oduduwa
(b) Esu
(d) Sango
18. _________ si ni oruko baba Oduduwa.
(a) Oya
(b) Lamurudu
(d) Osun
19. _____ ni won fi rin lati ilu meka ki won to tedo si ile- ife.
(a) ogbon
(b) Aadorun
(d) Ogun
20. Ile- Ife yii ni gbogbo omo _____ gba gege bi orirun wọn.
(a) ilo run
(b) Oyo
(d) Yoruba
21. Ninu iw kika “Emi loko iya won” Taa ni Durosomo majolate _____.
(a) Olori- Oko
(b) Oludari
(d) Oga
22. Taa ni morolayo _____.
(a) Iyawo
(b) Iyale- Asake
(d) Iyawo Keta
23. Taa ni Asake _____.
(a) Iya lambe
(b) Iya Kunle
(d) Iya- Aduke
24. Taa ni Adeolu- Alomaja _____.
(a) Aburo
(b) Egbon
(d) Ore-lambe
25. Taa ni afi orore weti Anobi Yusufu _____.
(a) Beyioku
(b) Deolu
(d) Bayo
26. Taa ni Tinuade _____.
(a) aburo – iya
(b) Ore- morolayo
(d) Egbon re
27. Iru ise woni Biliaminu nse nile ise ajumoni _____.
(a) Olopaa
(b) Ode- Asogba
(d) Loya
28. Taani Diran Ogun ola _____.
(a) Akowe- Owo
(b) Olode
(d) Oga
29. Bi Diran Ogun ola ti dara to _____ lo baje.
(a) iro
(b) Ole
(d) odaju
30. Taani Osundina _____.
(a) Awako
(b) Oga
(d) Loya
Ninu iwe- kika “ iji” dahun awon ibeere wonyi.
31. Iru iwa woni Taofeeki maa n hu _____.
(a) iwa-buburu
(b) iwa-ole
(d) iwa- ika
32. Salaye isele to sele ki sade to bimo _____.
(a) o subu
(b) Taofeeki ti subu
(d) O sun
33. Bawo ni Taofeeki se mo pe iyawo oun ti bimo _____.
(a) Ogbeni Biodun lo so fun
(b) Noosi
(d) Dokito
34. Ki loruko ti won so omo won _____.
(a) Lukmon
(b) Morufu
(d) Malik
Ninu iwe-kika “Temi Otan” dahun ibeere wonyi.
35. Egbe wo ni ogbonmipo tun dara po mo lati du ipo tuntun _____.
(a) Olobiripo
(b) Alalubosa
(d) Atunle se
36. Bawo ni Oritoke ati feyisayo se je si ara won _____.
(a) ore
(b) ebi
(d) obi
37. Ile Meloo ni ogbonmipo f eta lati dupo tuntun _____.
(a) meta
(b) mefa
(d) merin
38. Bawo ni ori toke seje nile ogbonmipo _____.
(a) omo-odo
(b) eru
(d) iyawo
39. Eniyan meloo ni ori ikilo ti a ko nipa omo ti oritoke fe bi _____.
(a) meji
(b) merin
(d) mefa
Ninu iwe- kika “ A ji mefun” dahun ibeere wonyi.
40. Daruko iwa ibaje ti awon akekoo buruku maa n hu _____.
(a) iranu
(b) ibaje
(d) oniregbe
41. _____ ni akewi menuba gege bi ijiya fun awon akekoo ti won n fi eko sere.
(a) Sofo
(b) Sere
(d) Padanu
42. Kinni akole miiran ti o le fun ewi yii _____.
(a) teramo –eko
(b) fojusi eko
(d) mo yin eko
Ninu iwe- kika “ Ajimefun” dahun ibeere wonyi.
43. Meloo ni akewi pe ni Aisan.
(a) Meta
(b) Merin
(d) Mefa
44. N je o gba pe olorun nii pa eniyan _____.
(a) beeni
(b) beeko
(d) nmo
Ninu iwe- kika “ Ayederu” dahun ibeere wonyi.
45. iru eniyan woni jibowu baba Ayobami _______
(a) Talaka
(b) Olowo
(d) Eru
46. So idi ti Tinu fi pinnu lati ba oyun je _____.
(a) Nitori ile- iwe re
(b) Nitori awon obi re
(d) Nitori itiju
47. Kinni o fa ede aiyede laarin Ayobami ati tinu _____.
(a) Nitori oyun re
(b) Nitori ija
(d) Nitori ibinu
48. Ninu iwe- kika Temiotan Nibo ni won gbe Omotuntun lo _____.
(a) ile
(b) ile- iwosan
(d) ile- babalawo
49. Abe igi wo ni won tiri omotuntun yii _____.
(a) igi-odan
(b) igi-osan
(d) igi- iroko
50. Taa ni eniti o gbe omo tuntun yii _____.
(a) Eniopetosi
(b) Enitan
(d) Oritoke
IPIN –KEJI
INSTRUCTION – DAHUN IBEERE META NINU IPIN YII.
Ninu iwe kika “Omi Obe danu dahun ibeere wonyi.
QUESTION 1
a. Olorun o ni je k iota raaye larin wa?
b. Mo se ami, mo gbe ito ami mi?
Ninu iwe-kika “Temiotan”.
d. Egbe wo ni Ogbonmipo tun dara po mo lati du ipo tuntun?
e. Bawo ni oritoke ati feyi sayo se je sira won?
Ninu- iwe –kika “ Ajimefun.
e. So meta lara aseyori oluko?
f. Nje ise oluko wu o (a) Beeni (b) Beeko
g. Ninu iwe- kika Awolowo _________ loruko mama ati baba Obafemi?
gb. Ojo _______ ni won bi Obafemi Awolowo?
QUESTION 2
a. Kin-in-ni Owe ni ile Yoruba?
b. Pa Orisii owe marun-un pere?
QUESTION 3. Itan Isedale Agbaalaye?
a. Ohun nla kan _____ bii boolu lo jabo.
b. Awon ibiti kofodeni odi odo _____ ati _____.
d. Won gba pe lati inu _____ ni eni yan ti wa.
e. itan orun oun _____ ni wonyi.
e. Kikida omini o _____ wan i ibere pepe.
QUESTION 4. Itan isedale Yoruba?
a. _____ ni babanla awon Yoruba.
b. Lamurudu si ni baba _____.
d. Omo meloo ni Oduduwa bii _____.
e. Ojo meloo ni won fir in lati ilu meka de ile ife _____.