Third Term Examination Yoruba Junior Secondary Schools – JSS 2 (Basic 8) Exam Questions
YORUBA THIRD TERM EXAMINATION FOR JUNIOR SECONDARY SCHOOLS – JSS 2 EXAM QUESTIONS
SECTION A- OBJECTIVES
INSTRUCTION – DAHUN GBOGBO IBEERE WONYI.
1. Asa-igbeyawo je irepo laarin ebi meji ________.
(a) Beeni
(b) Beeko
(d) Nmo
2. Awon oun igbese- igbeyawo won yii ________.
(a) Iwadii
(b) Ifo jusode
(d) Itoro
3. Pari owe yii “Afase gbe ojo n tan ________ re je.
(a) Ara
(b) Ebi
(d) Ore
4. Kinni onka “70” Lede Yoruba ni ________.
(a) Aadorin
(b) Ogbon
(d) Ogun
5. Ojo ________ ni awon obinrin fi maa n loyun.
(a) Mejo
(b) Mesan
(d) Mefa
6. Ojo keloo ni awon Yoruba somoloruko ________.
(a) Keje
(b) Kefa
(d) Kejo
7. Awon oun isomoloruko ni ________.
(a) Obi,Iyo
(b) ewe, igi
(d) ojo, owo
8. Awon oun idana ni ________.
(a) Isu Oyin
(b) So, owo
(d) Igi abo
9. Awon wo ni won maa n loyun ________.
(a) Obirin
(b) Omoge
(d) Odo
10. Omo bibi je oun ________ fun iya ikoko.
(a) Ayo
(b) Ibanuje
(d) Ike
11. Kinni eyan -Asonka Gbolohuin yii”ile merin ni mo ko ________.
(a) Ile
(b) Moko
(d) Merin
12. Kinni Eyan Asafihan gbolohunyii “Awon omo yen je meji” ________
(a) Yen
(b) Meji
(d) Omo
13. Kinni Eyan Asapejuwe gbolohun yii “omo pupa ni bola” ________.
(a) Omo
(b) Bola
(d) Pupa
14. Kinni eyan aropo-oruko gbolohun ________.
(a) Mi
(b) Iwe
(d) Lowo
15. Ohun mimo inu esin ibile Yoruba je esin awon ________.
(a) Abore
(b) Ifa
(d) Abalaye
16. ________ ni olori elesin abojuto ojubo ati ofin.
(a) Abore ati aworo
(b) Ifa
(d) Esin
17. Won gba wipe mimo ni ________.
(a) Eledumare
(b) Ifa
(d) Ofin
18. Okan lara Ere-idaraya ni ________.
(a) Igi
(b) Ewe
(d) Bojuboju
19. Awon ________ ni won maa n se Ere-idaraya.
(a) Omode
(b) Agbalagba
(d) Okunrin
20. Pari owe wonyi “Aja kii roro ko so ojule ________.
(a) Meta
(b) Ikan
(d) Meji
Ninu iwe – kika “Ija Biro ati bon” dahun ibeere yii.
21. Daruko gomina ti oda ile-ise meji kale ninu aye dun.
(a) Ojogbo olusoji Ajadi
(b) Kunle
(d) Dele
22. Daruko awon oga ile ise mejeeji naa ________.
(a) Olusoji Ajadi ati adenle ifalana
(b) Kunle ati dare
(d) Asogba
23. Taa ni ogbeni odebanji ________.
(a) Olopaa
(b) Asogba
(d) Ole
24. Bawoni ogbe ni yunusa Olasupo se ku ________.
(a) O tun asiri egbe okunku
(b) o ja won lole
(d) Ofo ila-ise bura
25. Iru eniyan wo ni ogbe ni – Ade dipe ________.
(a) Loya
(b) Soja
(d) Olopaa
26. Awon wo ni ogbe ni Ade dipe pe ni akowe ko wura ________.
(a) Awon o gege ara
(b) Elewa
(d) Oloor
27. Ta ni awon olopaa n pe ni osupa n tan mole.
(a) Ilu ayedun
(b) Oyo
(d) Epe
28. Ni bo ni Bolatito ti padee kasali ________.
(a) Eko
(b) Ilorin
(d) Ile Itura olomo
29. Eloo ni kasali fun Bolatito ________.
(a) Ogun-Naira
(b) Egberun marun
(d) Naira mewa
30. Nibo ni dokita jamiu Alabi tin sise.
(a) Ile
(b) Oko
(d) Ile-Iwosan
IPIN-KEJI
INSTRUCTION – DAHUN IBEERE META NINU IPIN YII.
QUESTION 1
A. Kin-in-ni Asa- igbeyawo?
B. Daruko igbese meta ninu Asa igbeyawo ati ohun elo marun pere?
QUESTION 2
A. Kin-in-ni Eyan?
B. Se apeere awon eyan wonyi?
D. Asonka apeere meji
E. Eyan- Asapejuwe meji?
Ẹ. Eyan- aropo-oruko meji?
QUESTION 3
A. Kin-in-ni Asa-isomoloruko?
B. Daruko ohun elo-isomoloruko mewa pere?
QUESTION 4
A. Asa-oyun nini ati itoju ikoko?
B. Awon wo ni won maa n loyun?
D. Ojo meloo ni obirin fi ma n loyun
E. Daruko oun marun-un ti won fi n toju ikoko?
Ẹ. Awon wo ni a n pe ni Agan?
F. Kinni o le fa agan yii so ni pare?
G. Eniyan meloo lawon egbe koloruko pa?
GB. Kinni oruko wale ola gan-an?d
H. Ile taani kasali lo ni gbati awon olopa tu sile
I. Nibo ni ogbe ni Rasidi ti n sise ?
J. Iru iran lowo wo ni ogbeni ajibola fe ki omowe adenle se fun oun?