Third Term Examination Yoruba Senior Secondary Schools (SS 1) Exam Questions

YORUBA THIRD TERM EXAMINATION SENIOR SECONDARY SCHOOLS (SS 1) EXAM QUESTIONS

SECTION A – OBJECTIVES

INSTRUCTION – CHOOSE THE CORRECT ANSWER FROM THE OPTIONS A – D.

1. Awon wo ni a maa n ko leta gbefe si ______.

(a) Odo

(b) Obi

(d) Ota

 

2. Adiresi meloo nil eta-gbefe ni ______.

(a) meji

(b) meta

(d) ikan

 

3. Apa ibo ni adiresi akoleta yoo wa ______.

(a) osi

(b) otun

(d) eyin

 

4. Kinni ipari Leta- gbefe ni ______.

(a) emi ni omo yiitooto

(b) emi omo

(d) tooto omo yii

 

5. Inu kinni leta yoo wan i ipari ______.

(a) iwe

(b) apo

(d) apo- iwe

 

6. Kinni oro- oruko oluwa ninu Gbolohun yii “ Kunle jeun yo” ______.

(a) jeun

(b) yo

(d) kunle

 

7. Kinni oro- oruko abo ninu Gbolohun yii “ mo je amala ______.

(a) amala

(b) je

(d) mo

 

8. Kinni oro- oruko eyan ninu Gbolohun yii “ Eja alaran” _______.

(a) alaran

(b) eja

(d) ran

 

9. Awon wo ni won maan sere idaraya ______.

(a) omode

(b) odo

(d) agba

 

10. Eniyan meloo ni won sere idaraya.

(a) Eni pupo

(b) Enikan

(d) Enimeji

 

11. Kinni onka yii lede Yoruba “100” _______.

(a) ogorun

(b) igba

(d) ogun

 

12. Pari owe wonyi “ malu ti ko niru ______ oba ni bale sin sin.

(a) oba

(b) olorun

(d) oluwa

 

13. Kinni oro- ise ninu gbolohun yii “ mo je iyan yo”.

(a) je

(b) mo

(d) mo

 

14. Kinni oro- aropo –oruko ninu gbolohun yii” mo ra aso ati bata.

(a) aso

(b) mo

(d) bata

 

15. Kinni oro- apejuwe ninu gbolohun yii ______“ Aso funfun ni baba wo”.

(a) funfun

(b) aso

(d) baba

 

16. Kinni oro- Atokun ninu gbolohun yii “ olu ilu Naijiria ni Abuja” ______.

(a) Olu

(b) Ni

(d) Naijiria

 

17. Kinni oro- Asopo ninu gbolohun yii “ Jide ati Titi je ore timo” ______.

(a) Titi

(b) Ore

(d) ati

 

18. Kinni oro- Aponle ninu gbolohun yii “ Bola rin kiakia”______.

(a) kiakia

(b) rin

(d) Bola

 

19. Kinni oro- aropo afarajoruko ninu gbolohun yii “ oun ni o ni iwe yen ______.

(a) yen

(b) oun

(d) iwe

 

20. Nibo ni won maa n gbe okulo sin ______.

(a) inu-ile

(b) saare

(d) ite-oku

 

21. Kinni oro-ise agbabo ninu gbolohun yii” kike mu fanta”______.

(a) mu

(b) kike

(d) fanta

 

22. Kinni oro- ise Alaigbabo ninu gbolohun yii “ Olorun wa” ______.

(a) Olorun wa

(b) wa

(d) Oluwa

 

23. Kinni oro- ise elela ninu gbolohun yii “ mo pa ile mo”______.

(a) pa x mo

(b) pa x de

(d) de x pa

 

24. Kinni oro- ise Alailela ninu gbolohun yii “ mo ranti ile”______.

(a) ran

(b) ile

(d) ranti

 

25. Kinni oro- ise Asebeere ninu gbolohun yii “ iye re n ko”______.

(a) nko

(b) re

(d) iya

 

NINU IWE KIKA ORE MI

INSTRUCTION – Dahun awon ibeere won yí. 

26. kinni oruko omo obirin ti Sola pade ninu ogba yunifasity.

(a) Sola

(b) Bukunmi

(d) Bose

 

27. Bawo ni Sola ati kunbi seje si ara won.

(a) Ota

(b) Aburo

(d) Ore

 

28. Kinni oruko baba Femi oloye ______.

(a) Opaleke Odunawo

(b) Akanji Ope

(d) Akintunde Oladele

 

29. Bawo ni Femi ati Sade se je si ara won ______.

(a) Egbon

(b) Ore

(d) Oko ati Aya

 

30. Kinni oruko baba sola ______.

(a) Kola Egbeda

(b) Kayode akinlolu

(d) Dele Odubanji

 

IPIN- KEJI

INSTRUCTION – DAHUN IBEERE META NINU IPIN YII. 

IBERE KINI

A. Kin-in-ni Ere- idaraya?

B. Daruko apeere Ere- idaraya marun-un se alaye meta pere?

 

IBERE KEJI

A. Kin-in-ni oro- ise se

B. Oro- ise eleyo kan apeere

D. Oro- ise Elela metameta

E. Oro- ise Alakanpo metameta

Ẹ. Oro- ise Alailela metameta

 

IBERE KETA

A. Kin-in-ni Oro- Oruko?

B. Se apeere oro-oruko Oluwa

D. Se apeere oro- Oruko abo

E. Se apeere oro- eyan mejimeji pere?

 

IBERE KẸRIN – NINU IWE KIKA ORE MI”

A. Daruko awon aburo Sola mẹta.

B. Omo meloo ni Sola bi fun Femi.

D. Ounje kunbi fe Femi bi.

(i) Beeni

(ii) Beeko

E. Nibo ni Kunbi ti lo pade Femi.

(i) Ilu oyinbo

(ii) Ilu Naigiria

Ẹ. Kini oruko omo ti kunbi2 bi fun Femi.