First Term Examination Yoruba (Yorùbá) Nursery 2 (Age 4)
YORUBA (Yorùbá)
FIRST TERM EXAMINATION
CLASS – NURSERY 2 (Age 4)
QUESTIONS
1. Ko alifabeeti yoruba A – GB.
2. Ko àpẹẹrẹ àwọn iro wonyii.
E ____
F ____
G ____
3. Kíkọ iro èdè ( g ) ni ede Yorùbá.
[a] gele
[b] aja
[c] dodo
4. Ko onka Yorùbá 6 je ______________.
[a] Eefa
[b] Eerin
[c] Eewa
5. Ọmọdé obìnrin ma n ______________ ki àgbàlagbà.
[a] dobale
[b] kunle
[c] sare o
6. Báwo ni a se ikinni ilẹ̀ yoruba ni òwúrò.
[a] E kaasan
[b] E kaaro
[c] Ekale
7. ______________ je orin akonilogbon.
[a] we ki o mo
[b] Ja dada
8. Kíkọ alifabeeti Yorùbá.
h i j k l m n o ọ
9. Dárúkọ àwọn wọ̀nyí.
l –
L –
10. Dárúkọ àwọn ohùn ti o wa ni ayika ti o mọ.