ÒNKA LÁTI ỌGỌ́RÙN DÉ IGBA
ÒNKA LÁTI ỌGỌ́RÙN DÉ IGBA
Number Nọ́mbà Number Nọ́mbà Number Nọ́mbà
1 ení 11 ọ̀kanlá 25 (30−5) ẹ́ẹdọ́gbọ̀n
2 èjì 12 (10+2) èjìlá 30 ọgbọ̀n
3 ẹ̀ta 13 (10+3) ẹ̀talá 35 (20×2−5) aárùndílogójì
4 ẹ̀rin 14 (10+4 ) ẹ̀rinlá 40 (20×2) ogójì
5 àrún 15 (20-5). ẹ́ẹdógún 50 (20×3−10) àádọ́ta
6 ẹ̀fà 16 (20-4) ẹẹ́rìndílógún 60 (20×3) ọgọ́ta
7 éje 17 (20-3) eétàdílógún 70 (20×4-10) àádọ́rin
8 ẹ́jọ 18 (20-2) eéjìdílógún 80 (20×4) ọgọ́rin
9 ẹ́sàn 19 (20-1) oókàndílógún 90 (20×5-10) àádọ́rùn
10 ẹ́wàá 20 ogún 100 (20×5) ọgọ́rùn › ọrún
110 (20×6-10) àádọ́fà
120 (20×6) ọgọ́fà
130 (20×7-10) àádóje
140 (20×2) ogóje
150 (20×8) àádọ́jọ
160 (20×8) ọgọ́jọ
170 (20×9−10) àádọ́sán
180 (20×9) ọgọ́sàn
190 (200-10) ẹ̀wadilúɡba
200 igba