Yorùbá Phrases
YORÙBÁ USEFUL PHRASES
English Yorùbá
- Welcome Ẹ ku abọ
- Hello/Hi Ẹ n lẹ
- How are you? Ṣe daadaa ni o wa?
- Do you speak English? Ṣe o le sọ èdè oyinbo?
- Do you speak Yoruba? Ṣe o n sọ Yorùbá?
- Where’s the toilet or bathroom? Nibo ni ile igbọnsẹ wa?
- How do you say ____ in Yoruba? Bawo ni o se le sọ ____ ni Yorùbá?
- I’m fine, thank you. And you? Mo wa daadaa, o ̣se. Iwọ naa n kọ?
- Long time, no see. O to ọjọ mẹta o. O pẹ ti a ri ara wa o.
- What’s your name? Ki ni orukọ rẹ?
- My name is Segun. Orukọ mi ni Segun.
- Where are you from? Nibo ni o ti wa?
- I’m from Lagos. Mo wa lati Lagos.
- Pleased to meet you. Inu mi dun lati mọ ọ.
- Good morning Ẹ ku aarọ
- Good afternoon Ẹ ku ọsan
- Good evening Ẹ ku alẹ
- Good night O da aarọ
- Goodbye O da abọ
- Good luck! Yoo dara o tàbí(or) Yoo bọ si o
- Cheers! Ayọ ni o
- Good Health! Kara o le
- Thank you O se (your mate or younger ones) or Ẹ ṣe (Elderly or two or more people)
- Call the police! Pe awọn ọlọpaa
- Merry Christmas Ẹ ku Ayọ Keresimesi
- Happy New Year Ẹ ku Ọdun Tuntun
- Happy Birthday Ẹ ku Ayọ Ọjọ Ibi
- Easter greetings Ẹ ku Ayọ Ajinde
- Congratulations! Oriire!
- Thank you Ko to ọpẹ
- Have a nice day. Oni a dara o
- Have a good journey. O da abọ tàbí (or) Ka sọ layọ o
- I understand O ye mi
- I don’t understand Ko ye emi
- Yes Bẹẹni
- Yes, a little Bẹẹni, diẹ
- No Bẹẹ kọ tàbí (or) Ó ti tàbí (or) Ra ra
- Maybe Boya
- Sorry Pẹlẹ
- I don’t know. N ko mo
- Please, speak more slowly. Jọwọ, rọra maa sọrọ
- Please, say that again. Jọwọ, tun un sọ
- Please, write it down. Jọwọ, kọ ọ silẹ
- Excuse me Ẹ jọwọ, ẹ gbọ mi
- How much is this? Eelo ni eyi?
- I miss you. Aro re so mi.
- I love you. Mo nifẹẹ rẹ
- Get well, soon. Da ara ya o
- Leave me alone! Fi mi silẹ
- Help! Ẹ gba mi o!
- Fire! Ina o!
- Stop! Duro nbẹ!