First Term Examination Yoruba/Yorùbá JSS 1 JSS 2 JSS 3 Exam Questions
YORUBA/YORÙBÁ
FIRST TERM EXAMINATION
JUNIOR SECONDARY SCHOOL
JSS 1 – JSS 2 – JSS 3 – Exam Questions
JSS 1 YORUBA/YORÙBÁ
Apa kinni – Dahun gbogbo awon ibeere wonyii
1. Ta ni baba n la awa Yoruba?
(a) Oduduwa
(b) Lamurudu
(d) Ile – Ife
2. Omo melo ni baba n Yoruba bi?
(a) Meta
(b) Meji
(d) Merin
3. Ta ni akobi?
(a) Eyo
(b) Oduduwa
(d) Otunyen
4. _________ ni awon Larubawa paaro oruko otunyen si.
(a) Okiki
(b) Buraimoh
(d) Oyo
5. Lati ibeere pepe ni awon Yoruba ti je _________.
(a) Musulumi
(b) Abogibope
(d) Igbagbo
6. _________ ni oruko Iyawo Okanbi.
(a) Latifa
(b) Omonide
(d) Sikemi
7. Opa _________ ni Oduduwa fi n segun awon ota.
(a) Igi
(b) Oranmiyan
(d) Onigi
8. Awon Yoruba fi _________ ojo rin de ile ti o fe.
(a) Aadowa
(b) Aadorun
(d) Ogun
9. Ile ti o fe ni a n pe ni _________ lode oni.
(a) Ileefe
(b) Ile-Ife
(d) Ile Ife
10. ________ ni o le awon Yoruba kuro ni meka.
(a) Ija owo
(b) Ija esin
(d) korana
11. Alifaabeti ede Yoruba je _________.
(a) medogun
(b) medogbon
(d) mewa
12. Iye konsonanti ede Yoruba je _________.
(a) meje
(b) mejidinlogun
(d) medogun
13. Nigbati faweli airanmupe je _________.
(a) meji
(b) meje
(d) meta
14. Faweli aranmupe je _________.
(a) mejo
(b) maarun
(d) merin
15. _________ ni ege oro ti eemi le gbe jade leekansoso.
(a) Ede
(b) silebu
(d) Ihun
16. Orisi Ikini _________ o wa ni ile Yoruba.
(a) mejo
(b) meta
(d) mewa
17. _________ ni lilo soke ati lilo sodo ohun eniyan nigbati a ba n se afo.
(a) Ami olorun
(b) Amin Ohun
(d) Ami Ohunun
18. Ewi _________ je Oriki fun awon Orisa Ile Yoruba.
(a) ajemayeye
(b) ajemesin
(d) Orin
19. Saaju Ojo ikomojade, a maa n pde omo ni _________.
(a) obìnrin
(b) arobo
(d) fine girl
20. Ff Gg _________ _________ _________.
IPA KEJÌ (SECTION B)
Dahun ibeere merin ni ipin yii.
ÌBÉÈRÈ KINI (QUESTION 1)
A. Se akosile gbogbo alifabeti ede Yoruba ni leta nla ati kekere.
B. Se Ikni fun awon wonyii:
i. Aaro – ii. Osan
iii. Igba Ojo
iv. Igba Oye
v. Onidiri
ÌBÉÈRÈ KEJÌ (QUESTION 2)
A. Ki silebu ni Oriki ?
B. So iye silebu ti awon oro wonyii ni:
i. Owo –
ii.Ogede –
iii. Otutu –
iv. Oniresi –
v. Ajemesin –
ÌBÉÈRÈ KẸTA (QUESTION 2)
A. Toka si iwulo ede maarun ti o mo.
B. Se akosile iwulo asa maarun ti o mo.
ÌBÉÈRÈ KẸRIN (QUESTION 4)
Sun Iyere Ifa kan ti o mo.
ÌBÉÈRÈ KÀRÚN (QUESTION 5)
Daruko awon Ohun eelo isomoloruko maarun ati bi a se n fi won sure si inu aye omo tuntun.
JSS 2 YORUBA/YORÙBÁ
Dahun gbogbo awon ibeere wonyii
Apa kinni
1. Awon obinrin nikan ni ise ile wa fun.
(a) Bẹẹni
(b) Beeko
(d) O fe jo be
2. Ifowosowopo nipa ise ile sise maa n mu _________ ba idile.
(a) ifasehin
(b) itiju
(d) itesiwaju
3. Ounje sise je ise _________ ninu ile.
(a) baba
(b) oluko
(c) iya
4. Gige koriko ayika ile je ise _________ ninu ile.
(a) baba
(b) iya
(c) baba baba
5. Ikini je ona Pataki lati _________ fun agbalagba.
(a) laju
(b) terbia
(d) buru
6. Iwa omoluabi je iwa ti o _________ lawujo.
(a) buru
(b) dara
(d) tini loju
7. Itoju ara je ona kan Pataki lati bori awon _________.
(a) ota
(b) aisan
(d) ole jija
8. Irun didi je osho fun awon _________ ni awujo.
(a) okunrin
(b) baba
(d) obinrin
9. O dara ki a maa n we ni _________.
(a) e kan lose
(b) emeji ni odun
(d) ojojumo
10. Ojo melon i o wa ninu ose?
(a) mewa
(b) mejila
(d) meje
11. _________ ni ojo akoko ni aarin ose.
(a) Ojo Aje
(b) Ojo Aiku
(d) Ojo bo
12. _________ ni ojo igbeyin ni aarin ose.
(a) Ojo Aiku
(b) Ojo Abameta
(d) Ojo ru
13. _________ ati _________ je ohun elo inu ile.
(a) Ope ati koriko
(b) Igbale ato abo
(d) Igala ati ijapa
14. Pari owe yii: Agbajowo lafi n _________.
(a) fe obinrin
(b) we owo
(d) sare
15. _________ je lara awon eniyan lawujo.
(a) Ijapa
(b) Omode
(d) Igala
16. _________ tumo si wipe ki eniyan ti to oju bo.
(a) Balaga
(b) Sare
(d) Dagba
17. Gbolohun _________ ni a fi n so bi nkan se ri.
(a)Alaye
(b) Ase
(d) Ibeere
18. _________ ni igbese akoko ninu Igbeyawo atijo.
(a) Ifojusode
(b) Iwadii
(d) Isihun
19.Ohun eelo ikoko mimo ni _________.
(a) iyepe amo
(b) aso
(d) owo
20. _________ ni eni ti o wa laarin afesona mejeeji leyin Isihun.
(a) Alarina
(b) Agba
(d) omode
APA KEJI (SECTION 2)
ÌBÉÈRÈ KINI (QUESTION 1)
A. Toka si onka ede Yoruba fun awon figo wonyii:
i. 40
ii. 42
iii. 53
iv . 62
v. 70
B. Se alaye ni kikun lori bi a se n mo ikoko.
ÌBÉÈRÈ KEJÌ (QUESTION 2)
Bawo ni ase n ki awon eniyan no awon akoko wonyii?
A. Igba ojo
B. Ogba eerun
D. Igba odun
ÌBÉÈRÈ KẸTA (QUESTION 3)
A. Ko awon ohun elo isomoloruko marun ti o mo.
B.Toka si oruko marun ti Yoruba n pe omo saaju ojo isomoloruko
JSS 2 YORUBA/YORÙBÁ
Apa kinni: Dahun gbogbo awon ibeere wonyii
1. _________ ni eto sise amulo iro ede Yoruba.
(a) Asinpo
(b) Yoruba
(d) Fonoloji
2. Asa _________ ni eye ikeyin ti Alaye maa n se fun oku, ki o to di asiko fifi eeru
fun eeru ati fifi eepe fun eepe.
(a) owo nina
(b) asa oye jije
(d) Isinku
3. Orisi Oku _________ lo wa.
(a) meta
(b) merin
(d) meji
4. Oku _________ ni oku omode.
(a) Arugbo
(b) Omidan
(d) Ofo
5. Ewi _________ ni irufe ewi ti a fi ohun didun se agbejade re.
(a) eranko
(b) ibile
(d) alohun
6. Ewi _________ ni irufe ewi fun awon orisa ile Yoruba.
(a) Alohun
(b) ajeniayeye
(d) Ajemesin
7. _________ ni arogun tabi arojinle ero okan wa, ti a si n se akosile re lori Ori Oro kan ni pato.
(a) Aroso
(b) Leta
(d) Aroko
8. Orisi aroko inu ede Yoruba je _________.
(a) mejo
(b) meje
(d) mefa
9. _________ ni eyo tabi akojopo oro ihun kan.
(a) Awe gbolohun
(b) Irunmale
(d) Apola
10. A maa n lo apola ise gege bi a se n lo oro-ise.
11. _________ ni apa kan lati ara odindi gbolohun.
(a) Apola
(b) Aroko
(d) Awe gbolohun
12. _________ ni akojopo oro ogbon lati enu awon baba n la wa.
(a) Aaro
(b) Ebese
(d) Owe
13. _________ je ‘Se fun mi, ki n se fun o’ti won fe ni.
(a) Owe
(b) Ebese
(d) Aaro
14. Irufe Irannilowo ti eni ti o be ise maa n pese ohun ti won fe ni _________.
(a) Aaro
(b) Ebese
(d) Owo
15. Owu ya gbon _________.
(a) ni baba ngbe
(b) legbon n je
(d) lomoran
16. 40 ni _________ ni ede Yoruba.
(a) ogbon
(b) ogun
(d) ogoji
17. _________ ni oba Irin.
(a) Sango
(b) Orunmila
(d) Ogun
18. 39 = __________
(a) okanlelemeta
(b) eeta ati esan
(d) okandinlogoji
19. _________ je apeere ounje ile Yoruba.
(a) Banga
(b) luuru
(d) Iyan
20. Orisi awe gbolohun je _________.
(a) mejo
(b) meta
Kd) meji
IPA KEJI (SECTION B)
Dahun ibeere merin ni ipin yii.
ÌBÉÈRÈ KINI (QUESTION 1)
A. Ki fonoloji ni oriki?
B. Daruko orisi oku meji ti o mo? Ki o si se alaye okan ninu won.
ÌBÉÈRÈ KEJÌ (QUESTION 2)
2. Se akosile ewi alohun ajeni esin kan ti o mo.
ÌBÉÈRÈ KẸTA (QUESTION 3)
A. Ki aroko ni oriki.
B. Toka si orisi aroko maarun ti o mo.
ÌBÉÈRÈ KẸRIN (QUESTION 4)
A. Toka si owe ile Yoruba maarun ti o mo.
B. Daruko igbese isinku arugbo maarun-un ti o mo.
ÌBÉÈRÈ KÀRÚN (QUESTION 5)
A. Ki isinku ni oriki.
B. Se alaye ni soki lori awon wonyii:
i. Aaro
ii. Owe
iii. Esusu